Nọ́ḿbà 31:41 BMY

41 Mósè fi ìdá náà fún Élíásárì, àlùfáà gẹ́gẹ́ bí ìdá ti Olúwa, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:41 ni o tọ