Nọ́ḿbà 31:5 BMY

5 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì yan nínú àwọn ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn Ísírẹ́lì, ẹgbẹ̀rún (1000) ènìyan láti inú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, ẹgbàá mẹ́fà (12,000) ènìyàn tí ó wọ ìhámọ́ra ogun.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:5 ni o tọ