Nọ́ḿbà 33:1 BMY

1 Wọ̀nyí ni ìrìnàjò àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ẹsẹẹsẹ, nígbà tí wọ́n tí ilẹ̀ Íjibítì jáde wá pẹ̀lú àwọn ogun wọn, nípa ọwọ́ Mósè àti Árónì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 33

Wo Nọ́ḿbà 33:1 ni o tọ