Nọ́ḿbà 33:38 BMY

38 Nípa àsẹ Olúwa, Árónì àlùfáà gùn orí òkè Hórì, níbẹ̀ ni ó kú. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kárun, ọdún ogójì, lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti ilẹ̀ Éjíbítì jáde wá.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 33

Wo Nọ́ḿbà 33:38 ni o tọ