Nọ́ḿbà 33:52 BMY

52 Lé gbogbo àwọn ará ilẹ̀ náà kúrò níwájú yín. Run gbogbo àwòrán ère wọn àti gbogbo ère dídá wọn, kí ẹ sì wó gbogbo ibi gíga wọn palẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 33

Wo Nọ́ḿbà 33:52 ni o tọ