20 Ṣémúélì ọmọ Ámíhúdì,láti ẹ̀yà Ṣíméónì;
21 Élídádì ọmọ Kísílónì,láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì;
22 Búkì ọmọ Jógílì,láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dánì;
23 Háníélì ọmọ Éfódù,láti ẹ̀yà Mánásè, olórí àwọn ọmọ Jóṣẹ́fù,
24 Kémúélì ọmọ Ṣífílánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Éfúráímù, ọmọ Jóṣẹ́fù;
25 Élísáfánì ọmọ Pánákì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ṣébúlunì;
26 Pátíélì ọmọ Ásánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákárì;