24 Kémúélì ọmọ Ṣífílánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Éfúráímù, ọmọ Jóṣẹ́fù;
25 Élísáfánì ọmọ Pánákì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ṣébúlunì;
26 Pátíélì ọmọ Ásánì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákárì;
27 Áhíhúdù ọmọ Ṣélómì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Áṣérì;
28 Pédàhẹ́lì ọmọ Ámíhúdì,olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfitalì.”
29 Èyí ni àwọn ẹni tí Olúwa yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ Kénánì.