Nọ́ḿbà 35:12 BMY

12 Wọn yóò jẹ́ ibi ìsásí kúrò lọ́wọ́ olùgbẹ̀san, kí ẹní tí a fi ẹ̀sùn ìpànìyàn kàn má baà kú kí ó tó dúró níwájú àwọn ìjọ àwọn ènìyàn ní ìdájọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:12 ni o tọ