Nọ́ḿbà 35:6 BMY

6 “Mẹ́fà lára ìlú tí ẹ fún àwọn ọmọ Léfì yóò jẹ́ ìlú ibi ìsásí, tí ẹni tí ó bá pa ènìyàn yóò sá sí. Ní àfikún, ẹ fún wọn ní méjìlélógójì (42) ìlú sí i.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:6 ni o tọ