Nọ́ḿbà 36:6 BMY

6 Èyí ni ohun tí Olúwa pàṣẹ fún àwọn ọmọbìnrin Ṣélófíhádì: Wọ́n lè fẹ́ ẹni tí ọkàn wọn fẹ́, kìkì pé wọ́n fẹ́ nínú ẹ̀yà ìdílé baba wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 36

Wo Nọ́ḿbà 36:6 ni o tọ