Nọ́ḿbà 4:28 BMY

28 Èyí ni iṣẹ́ ìdílé àwọn Gáṣónì ni Àgọ́ Ìpàdé Ítamárì, ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà ni yóò sì jẹ alábojútó iṣẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:28 ni o tọ