Nọ́ḿbà 4:33 BMY

33 Èyí ni iṣẹ́ ìsìn ìdílé àwọn ọmọ Mérárì, bí wọn yóò ti máa ṣiṣẹ́ ní Àgọ́ Ìpàdé lábẹ́ àkóso Ítamárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:33 ni o tọ