Nọ́ḿbà 4:5 BMY

5 Nígbà tí àgọ́ yóò bá tẹ̀ṣíwájú, Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò wọ inú rẹ̀, wọn yóò sí aṣọ ìbòrí rẹ̀, wọn yóò sì fi bo àpótí ẹ̀rí.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:5 ni o tọ