Nọ́ḿbà 5:28 BMY

28 Ṣùgbọ́n tó bá jẹ́ pé obìnrin náà kò ba ara rẹ̀ jẹ́, tó sì jẹ́ mímọ́, yóò bọ́ nínú ẹ̀bi, yóò sì le bímọ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 5

Wo Nọ́ḿbà 5:28 ni o tọ