Nọ́ḿbà 6:3 BMY

3 Irú ẹni bẹ́ẹ̀ gbọdọ̀ yàgò fún wáìnì tàbí ọtí líle, ọtí wáìnì kíkan àti àwọn ohun mímu mìíràn tó bá kan. Kò gbọdọ̀ mu èso àjàrà tàbí kí ó jẹ èṣo àjàrà tútù tàbí gbígbẹ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 6

Wo Nọ́ḿbà 6:3 ni o tọ