Nọ́ḿbà 7:1 BMY

1 Nígbà tí Móṣè ti pári gbígbé àgọ́ dúró, ó ta òróró sí i, ó sì yà á sí mímọ́ pẹ̀lú gbogbo àwọn ohun èlò rẹ̀, Ó tún ta òróró sí pẹpẹ, ó sì yà á sí mímọ́ pẹ̀lú gbogbo ohun èlò rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:1 ni o tọ