Nọ́ḿbà 7:84 BMY

84 Wọ̀nyí ni ọrẹ tí àwọn olórí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mú wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ nígbà tí wọ́n ta òróró sí i lórí: àwo fàdákà méjìlá, àwokòtò méjìlá, àwo wúrà méjìlá.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:84 ni o tọ