Nọ́ḿbà 8:21 BMY

21 Àwọn ọmọ Léfì wẹ ara wọn mọ́, wọ́n sì fọ aṣọ wọn. Árónì sì mú wọn wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fífì níwájú Olúwa, Árónì sì ṣe ètùtù fún wọn láti wẹ̀ wọ́n mọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:21 ni o tọ