Nọ́ḿbà 8:3 BMY

3 Árónì sì ṣe bẹ́ẹ̀; ó to àwọn fìtílà náà tí wọ́n sì fi kojú ṣíwájú lórí ọ̀pá fìtílà gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:3 ni o tọ