Nọ́ḿbà 9:17 BMY

17 Nígbàkígbà tí ìkúùkù yìí bá ká sókè kúrò lórí àgọ́ ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò dìde láti máa lọ; ibikíbi tí ìkúùkù náà bá dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò pa ibùdó wọn sí.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 9

Wo Nọ́ḿbà 9:17 ni o tọ