Nọ́ḿbà 9:23 BMY

23 Nípa àṣẹ Olúwa ni wọ́n ń pa ibùdó wọn, nípa àṣẹ Olúwa náà sì ni wọ́n ń gbéra. Wọ́n gbọ́ràn sí àṣẹ Olúwa ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ Olúwa láti ẹnu Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 9

Wo Nọ́ḿbà 9:23 ni o tọ