Nọ́ḿbà 9:6 BMY

6 Àwọn díẹ̀ nínú wọn kò lè ṣe àjọ Ìrékọjá lọ́jọ́ náà nítorí pé wọ́n di aláìmọ́ nítorí òkú ènìyàn. Nítorí èyí wọ́n wá sọ́dọ̀ Mósè àti Árónì lọ́jọ́ náà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 9

Wo Nọ́ḿbà 9:6 ni o tọ