Onídájọ́ 1:20 BMY

20 Gẹ́gẹ́ bí Móṣè ti ṣèlérí, wọ́n fún Kélẹ́bù ní Hébírónì ó sì lé àwọn tí ń gbé ibẹ̀ kúrò; àwọn náà ni ìran àwọn ọmọ Ánákì mẹ́ta.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:20 ni o tọ