Onídájọ́ 11:24 BMY

24 Ǹjẹ́ ìwọ kì yóò ha gba èyí tí Kémọ́sì òrìṣà rẹ fí fún ọ? Bákan náà àwa yóò gba èyíkéyìí tí Olúwa Ọlọ́run wa fi fún wa.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:24 ni o tọ