Onídájọ́ 12:3 BMY

3 Nígbà tí mo ríi pé ẹ̀yin kò ṣetán láti ṣe ìrànlọ́wọ́, mo fi ẹ̀mi mi wéwu. Mó sì gòkè lọ láti bá àwọn ará Ámónì jà, Olúwa sì fún mi ní ìṣẹ́gun lórí wọn, Èéṣe báyìí tí ẹ fi dìde wá lónìí láti bá mi jà?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 12

Wo Onídájọ́ 12:3 ni o tọ