Onídájọ́ 12:4 BMY

4 Jẹ́fítà sì pe àwọn ọkùnrin Gílíádì, wọ́n sì bá àwọn ará Éfúráímù jà. Àwọn ará Gílíádì run wọ́n nítorí pé àwọn ará Éfúráímù ti ṣọ tẹ́lẹ̀ pé, “Ẹ̀yin ará Gílíádì jẹ́ àṣáwọ̀ (ìṣáǹṣá) àwọn ará Éfúráímù àti ti Mànásè.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 12

Wo Onídájọ́ 12:4 ni o tọ