Onídájọ́ 12:5 BMY

5 Àwọn ará Gílíádì gba àbáwọdò Jọ́dánì tí wọ́n máa gbà lọ sí Éfúráímù, nígbàkígbà tí àwọn ará Éfúráímù bá wí pé, “Jẹ́ kí ń sá lọ sí òkè,” lọ́hùn ún àwọn ará Gílíádì yóò bi í pé, “Ṣé ará Éfúráímù ni ìwọ ń ṣe?” Tí ó bá wí pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́,”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 12

Wo Onídájọ́ 12:5 ni o tọ