Onídájọ́ 13:11 BMY

11 Mánóà yára dìde, ó sì tẹ̀lé aya rẹ̀, nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ ọkùnrin náà ó ní, “Ǹjẹ́ ìwọ ni o bá obìnrin yìí sọ̀rọ̀?”Ọkùnrin náà dáhùn pé “Èmi ni.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:11 ni o tọ