Onídájọ́ 13:12 BMY

12 Mánóà bi ọkùnrin náà pé, “Nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ kí ni yóò jẹ́ ìlànà fún ìgbé ayé àti iṣẹ́ ọmọ náà?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 13

Wo Onídájọ́ 13:12 ni o tọ