Onídájọ́ 18:31 BMY

31 Wọ́n tẹ̀ṣíwájú láti lo àwọn ère tí Míkà ṣe, ní gbogbo àkókò tí ilé Ọlọ́run wà ní Ṣílò.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 18

Wo Onídájọ́ 18:31 ni o tọ