Onídájọ́ 19:1 BMY

1 Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì Ísírẹ́lì kò ní ọba.Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Léfì tí ń gbé ibi tí ó sápamọ́ nínú àwọn agbégbé òkè Éfúráímù, mú àlè kan láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ní Júdà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:1 ni o tọ