Onídájọ́ 19:17 BMY

17 Nígbà tí ó wòkè ó rí arìnrìnàjò náà ní gbọ̀ngàn ìlú náà, ọkùnrin arúgbó yìí bi í léèrè pé, “Níbo ni ò ń lọ? Níbo ni o ti ń bọ̀?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:17 ni o tọ