Onídájọ́ 19:18 BMY

18 Ọmọ Léfì náà dá a lóhùn pé, “Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Júdà ni àwa ti ń bọ̀, àwa sì ń lọ sí agbégbé tí ó sápamọ́ ní àwọn òkè Éfúráímù níbi ti mo ń gbé. Mo ti lọ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Júdà, èmi sì ń lọ sí ilé Olúwa nísinsìn yìí. Kò sí ẹni tí ó gbà mí sí ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 19

Wo Onídájọ́ 19:18 ni o tọ