Onídájọ́ 2:3 BMY

3 Ní báyìí, èmi wí fún un yín pé, èmi kì yóò lé àwọn ènìyàn jáde kúrò níwájú yín; ṣùgbọ́n wọn yóò jẹ́ ẹ̀gún ní ìhà yín, àwọn òrìṣà wọn yóò sì jẹ́ ìdánwò fún un yín.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:3 ni o tọ