Onídájọ́ 2:4 BMY

4 Bí ańgẹ́lì Olúwa sì ti sọ gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àwọn ará Ísírẹ́lì tan, àwọn ènìyàn náà sì gbé ohùn wọn sókè wọ́n sì sunkún kíkorò,

Ka pipe ipin Onídájọ́ 2

Wo Onídájọ́ 2:4 ni o tọ