Onídájọ́ 3:4 BMY

4 A fi àwọn ènìyàn náà sílẹ̀ láti dán àwọn Ísírẹ́lì wò bóyá wọn yóò gbọ́ran sí àwọn òfin Olúwa, èyí tí ó ti fi fún àwọn baba wọn láti ipaṣẹ̀ Móṣè.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 3

Wo Onídájọ́ 3:4 ni o tọ