Onídájọ́ 6:14 BMY

14 Olúwa sì yípadà sí i, ó sì wí fún un pé, “Lọ nínú agbára tí o ní yìí, kí o sì gba àwọn ará Ísírẹ́lì sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Mídíánì. Èmi ni ó ń rán ọ lọ.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:14 ni o tọ