Onídájọ́ 8:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n Gídíónì dá wọn lóhùn pé, “Èmi kì yóò jọba lórí yín, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ mi kì yóò jọba lórí yín. Olúwa ni yóò jọba lórí yín.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:23 ni o tọ