Onídájọ́ 8:28 BMY

28 Báyìí ni a ṣe tẹrí àwọn ará Mídíánì ba níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ́ẹ̀ ni wọn kò tún gbérí mọ́. Ní ọjọ́ Gídíónì, Ísírẹ́lì wà ní àlàáfíà fún ogójì ọdún.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:28 ni o tọ