Ìfihàn 1:13 BMY

13 Àti láàrin àwọn ọ̀pá fìtílà náà, ẹnìkan tí ó dà bí “ọmọ ènìyàn,” tí a wọ̀ ní aṣọ tí ó kanlẹ̀ dé ẹṣẹ̀, tí a sì fi àmùrè wúrà dì ní ẹ̀gbẹ́.

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:13 ni o tọ