Ìfihàn 1:18 BMY

18 Èmi ni ẹni tí ó ń bẹ láàyè, tí ó sì ti kú; sì kíyèsí i, èmi sì ń bẹ láàyè sí i títí láé! Mo sì ní kọ́kọ́rọ́ ikú àti ti ipò-òkú.

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:18 ni o tọ