10 Mo sì gba ìwé kékeré náà ni ọwọ́ ańgẹ́lì náà mo sì jẹ ẹ́ tan; ó sì dùn lẹ́nù mi bí oyin; bí mo sì tí jẹ ẹ́ tan, inú mi korò.
Ka pipe ipin Ìfihàn 10
Wo Ìfihàn 10:10 ni o tọ