Ìfihàn 10:8 BMY

8 Ohùn náà tí mo gbọ́ láti ọ̀run tún ń ba mi sọ̀rọ̀, ó sì wí pé, “Lọ, gba ìwé tí a ṣí náà lọ́wọ́ ańgẹ́lì tí o dúró lórí òkun àti lórí ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 10

Wo Ìfihàn 10:8 ni o tọ