Ìfihàn 12:1 BMY

1 Àmì ńlá kan sì hàn ni ọ̀run; obìnrin kan tí a fi òòrùn wọ̀ ní aṣọ, òṣùpá sì ń bẹ lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá sì ń bẹ lórí rẹ̀:

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:1 ni o tọ