Ìfihàn 12:3 BMY

3 Àmì mìíràn sì hàn lọ́run; sì kíyèsí i, dírágónì pupa ńlá kan, tí ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, àti adé méje ní orí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:3 ni o tọ