Ìfihàn 12:5 BMY

5 Ó sì bi ọmọkùnrin kan tí yóò fi ọ̀pá irin ṣe àkóso gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè: a sì gba ọmọ rẹ̀ lọ sókè sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, àti sí orí ìtẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:5 ni o tọ