Ìfihàn 13:13 BMY

13 Ó sì ń ṣe ohun ìyanu ńlá, àní tí ó fi ń mú iná sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá sì ilẹ̀ ayé níwájú àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:13 ni o tọ