Ìfihàn 13:3 BMY

3 Mo sì rí ọ̀kan nínú àwọn orí rẹ̀ bí ẹni pé a ṣá a pa, a sì tí wo ọgbẹ́ àṣápa rẹ̀ náà sàn, gbogbo ayé sì fi ìyanu tẹ̀lé ẹranko náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:3 ni o tọ