Ìfihàn 13:5 BMY

5 A sì fún un ni ẹnu láti má sọ ohun ńlá àti ọ̀rọ̀ òdì, a sì fi agbára fún un láti ṣe bẹ́ẹ̀ ni oṣù méjìlélógójì.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:5 ni o tọ