Ìfihàn 13:7 BMY

7 A sì fún-un láti máa bá àwọn ènìyàn-mímọ́ jagun, àti láti ṣẹ́gun wọn: a sì fi agbára fún un lórí gbogbo ẹ̀yà, àti ènìyàn, àti èdè, àti orílẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:7 ni o tọ